Àkójọpọ̀ èsì ìdìbò gómìnà ìpínlẹ̀ Ondo

Awọn oludije sipo gomina
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Eyi ni bi awọn esi ibo gomina ṣẹ n jade lati ijọba ibilẹ kọọkan nipinlẹ Ondo.

Ti o ba ṣe n tẹ ori maapu to wa ni isalẹ, ni abajade esi ibo fun ẹgbẹ oṣelu kọọkan, pẹlu ijọba ibilẹ ti wọn ti bori, yoo maa han si ọ.