You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Kí ni ẹ̀tọ́ tí àlè tàbí obìnrin sérékodé ìkọ̀kọ̀ ní sí ogún olóògbé?
Kí ni ẹ̀tọ́ tí àlè tàbí obìnrin sérékodé ìkọ̀kọ̀ ní sí ogún olóògbé?
Ṣe awọn ale ati anti ẹgbẹ kọọrọ tilẹ lẹtọ si dukia ọkunrin ti wọn jumọ jọ ni ifẹ ikọọkọ bi ọkunrin naa ba di oloogbe bi?
Ibeere yii lo jẹyọ nitori awọn iṣẹlẹ kan to n ṣẹ lawujọ, eleyi to ti mu ki ariyanjiyan o maa waye loriọrọ naa lori ayelujara.
Eyi lo mu ki BBC News Yoruba tọ awọn to ni imọ lọ lati le wa idahun si ohun to ṣokunkun si ọpọ lori ọrọ yii.
Ninu fidio yii, amofin kan ṣalaye ohun ti ofin sọ nipa ipa to kan awọn ale, ololufẹ ikọkọ tabi gbangba to ba bimọ fun ọkunrin ololufẹ rẹ ninu iwe ipingun ti ololufẹ wọn bẹẹ ba fi silẹ lẹyin iku wọn.