Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Wo, ẹ san owo gba mabinu fawọn ẹbi awọn ọdẹ mẹrindinlogun tawọn ara ilu Uromi ṣekupa lọsẹ to kọja

Gomina ipinlẹ Kano, Abba Yusuf lo sọ bẹẹ fun gomina ipinlẹ Edo, Monday Okpebholo

Lasiko to ṣabẹwo ibanikẹdun lọ si Kano lọjọ Aje

Gomina Abba Yusuf ni ṣiṣe eyi ati fifoju awọn to huwa naa wina ofin

Lo le tan iṣẹlẹ ọhun lọkan awọn ẹbi

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Awuyewuye lorilẹ ede Amẹrika

Bi Trump ṣe sọrọ lori ipinnu rẹ lati ṣe saa kẹta gẹgẹ bi aarẹ

Bi o tilẹ jẹ pe ofin Amẹrika ko faaye gba ki aarẹ kankan lo saa mẹta lori ipo

Awọn alatileyin Trump ni ọna wa lati gbe e gba

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Bi n ba sọ fun ọ pe wiwa ninu oorun ni nnkan bii aago mejila ọsan dara fun agọ ara a rẹ

April fool

Ọrọ ẹtan ma kọ ni eyi, iwadii awọn onimọ sọ pe wiwa ninu oorun maa n din ẹjẹ ruru ku, mu egungun ati iṣan ara le si ati pe o maa n fun ara n vitamin D

Ṣe ka ma wa jokoo sabẹ oorun lo n sọ bayii?

Fun ẹkunrẹrẹ alaye

Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́