Nítorí ìpèníjà, àwọn òbí fúnrawọn máa ń kó ọmọ fún ilé ọmọ aláìníyá wa – Febishola Okonkwo, adarí Tabitha Homes

Nítorí ìpèníjà, àwọn òbí fúnrawọn máa ń kó ọmọ fún ilé ọmọ aláìníyá wa – Febishola Okonkwo, adarí Tabitha Homes

Arabinrin Fẹbiṣọla Ọladimeji Okonkwov to jẹ alakoso ile awọn ọmọ alainiya Tabitha homes ni igba miran awọn obi ti agbara wọn ko ka ati tọ ọmọ wọn maa n pe wọn lati wa gbe awọn ọmọ wọnyii si ọdọ.

O fi kun un pe nigba miran awọn agbofinro lo maa n fi ọrọ naa to wọn leti nipa awọn ọmọ ti wọn ba ri lati wa ni ikawọ wọn fun itju.

Arabinrin Okonkwo ṣalaye pe awọn ileeṣẹ aladani atawọn to mọ riri iṣẹ ti ile ọmọ alainiya naa n ṣe ni wọn n na ọwọ iranwọ si ile naa.