Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ibadan ọmọ Agbọtikuyọ
Latana ni ariwo ilu ti n sọ nile gomina tẹlẹ ri ni ipinlẹ Oyo, Rasheed Ladoja
Ti wọn si n ki ku imura ati gori apere Olubadadan
Gbọ na, ṣe bi ana ni Olubadan ṣẹṣẹ waja, ṣo yẹ ki wọn ti maa ṣajọyọ ni?
Kan soju opo bbcnews.com/Yoruba lati ka ẹkunrẹrẹ iroyin nipa oye Olubadan
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Ìròyìn ayọ̀!
Oogun itọju aisan iba fawọn ọmọ ti ri ibuwọlu
Oògùn náà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Coartem Baby tàbí Riamet Baby
Ni wọn yoo bẹrẹ si ni pin sawọn ilẹ Africa laaarin ọsẹ diẹ si asiko yii
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Eeyan mọkanla jade laye, ti ọpọ si dero atimọle
Lasiko ti wọn n ṣe iwọde 7-7 lorilẹ ede Kenya
lati ṣami ayajọ ọdun karundinlogoji Saba-Saba
nibi ti awọn eeyan Kenya ti pe fun ọpọ ẹgbẹ oṣelu ninu ijọba awarawa
