Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Nibo lo n lọ, ti o ro dudu ti o kan dẹdẹ bayii?

Ilu Oyo kuku ni mo n lọ, mo fẹ lọ bawọn ṣayẹyẹ iwuye Alaafin tuntun

Ijọba ipinlẹ Oyo ni gbogbo eto lo ti wa ni sẹpe

Tawọn ẹṣọ aabo naa si duro digbi kaakiri gbogbo ibi to ṣe koko

Ṣe oni ni?

Rara o, Ọla ode yii, ọjọ́ Karun-un ni eto naa yoo waye lawọn aaye mẹrin

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Diẹ lo ku kawọn ikooko ṣekupa mi lakata ajinigbe

Adari tẹlẹ ri fun NYSC, Maharazu Tsiga lo sọ bẹẹ nigba to n sọ iriri rẹ lahamọ ajinigbe

Tsiga to lo ọjọ mẹrindinlọgọta ni ahamọ awọn ajinigbe ṣalaye pe

Niṣe ni awọn ajinigbe naa n lo awọn lati da aabo ara wọn lọwọ awọn ẹṣọ aabo

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

To ba ti to asiko to yẹ maa fi awọn ẹri ẹsun bi Akpabio ṣe n fi ibalopọ lọ mi lede

Sẹnetọ Natasha Akpoti-Uduaghan lọ sọ bẹẹ

O ni o dun mọ oun pe INEC ti da iwe ipe tawọn kan fẹ fi pe oun kuro nile aṣofin nu

Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́