Hauwa Lawal, gbajúmọ̀ lórí ayélujára dá sí 'Sóo láyà?'
Hauwa Lawal, gbajúmọ̀ lórí ayélujára dá sí 'Sóo láyà?'
Gbajumọ ori ayelujara ni Hauwa Lawal. BBC News Yoruba dan an wo pẹlu awọn ibeere nipa ede Yoruba lati mọ bi o ṣe jafafa si.
Ẹyin ololufẹ rẹ ati ti BBC News naa lẹ le fun ni maaki lẹyin ti ẹ ba ti jẹgbadun rẹ pẹlu ẹrin keekee.
Ṣé Hauwa Lawal láyà tàbí kò láyà, ó yá ẹ̀yin náà ẹ wòó




