Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ṣe o ranti ibugbamu to waye niluu Ibadan lọdun to kọja nibi ti ẹmi ti sọnu, ti ọpọ dukia si bajẹ?
Bẹẹni o, mo ranti daadaa
BBC Yoruba ti kan si ijọba Oyo atawọn ti ọrọ naa kan lati mọ bi nnkan ṣe ri lẹyin iṣẹlẹ ọhun
Iyẹn naa daa, ki ni wọn sọ?
Lọ soju opo wa fun ẹkunrẹrẹ
Iwadi iku olorin takasufe, Mohbad, ti gbọna mii yọ laarin iya rẹ ati oṣere tiata Yoruba, Yomi Fabiyi
Ibi apero awọn akọroyin kan to waye niluu Ẹko lati wa kulẹkulẹ ohun to ṣokunfa iku olorin naa ni gbọnmi si omi o to ti bẹ silẹ laarin wọn
Fabiyi ni ija Mohbad loun n ja
Amọ iya oloogbe naa ni oun ko fẹ ki wọn pa ọmọ oun mii bi wọn ṣe pa Mohbad
Ọmọọọba Lukman Gbadegesin tí Oyomesi fòǹtẹ̀ lù láti di Aláàfin Oyo ti fáàké kọ́rí
Lẹyin ti gomina Seyi Makinde gbe ọpa aṣẹ fun ọmọọba Akeem Owoade
Ọmọ Ọba naa atawọn afọbajẹ marun ti fun Makinde ni ọgbọn ọjọ pere lati gba ọpa aṣẹ naa pada ko si gbe fun ẹni ti wọn n fẹ