"Nítorí mo tako ìjọba, wọ́n gbé mi lọ sílé ìwòsàn fún ìtọ́jú àrùn ọpọlọ"

Àkọlé fídíò, Nítorí mo tako ìjọba, wọ́n gbé mi lọ sílé ìwòsàn fún ìtọ́jú àrùn ọpọlọ-
"Nítorí mo tako ìjọba, wọ́n gbé mi lọ sílé ìwòsàn fún ìtọ́jú àrùn ọpọlọ"

Nigba ti Junji wa ni ọmọ ọdun mẹtadinlogun , o darapọ mọ ifẹhonuhan ni ita fasiti rẹ lati tako ofin ijọba China. Lẹyin bi ọjọ meloo, wọn gbe lọ si ile iwosan fun aarun apọlọ, ti wọn si n tọju rẹ fun aisan ọpọlọ.

Junjie jẹ ọkan ninu ọpọ eeyan ti BBC ba sọrọ lẹyin ti wọn dero ile iwosan aarun ọpọlọ lẹyin ti wọn se ifẹhonuhan tako ijọba.

Awọn eeyan ti ba sọrọ ni wọn fun ni oogun aisan ọpọlọ, ti wọn si gbe sinu ẹrọ ECT lia ba wọn sọ tẹlẹ.

Junjie ni ilukulu ni awọn oṣiṣẹ ile iwosan lu oun ko to di pe wọn fi tipatipa fun oogun aisan ọpọlọ.

Ẹkunrere alaye nipa iwadii BBC wa ninu fidio ti a ti pese soke.

Aworan oogun