You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Children games Akomolede àti Asa: Wa wo èré èyí tó yẹ fún àárọ̀ kùtù àti èyi tó wà fún òṣùpá
"Ẹkun mẹẹran, mẹẹ, o mu dudu, mẹ́ẹ, o mu pupa, mẹẹ..."
Pẹlu apẹrẹ lawọn akẹkọọ naa fi darapọ mọ eto ti tonii lati ṣe ere idaraya "bojuboju o".
Ọmọwe lo n kọ wa lori eto Akomolede ati Aṣa Yoruba tonii. Ọmọwe Yetunde Olaleye-Awolusi lati ileewe Chirist Way High School niluu Ile Ife lo mu wa lọ si iranti bi ere idaraya ṣe maa n ri laye atijọ.
Yoruba gbagbọ pe lẹyin iṣẹ oojọ, o yẹ ki isinmi ati igbadun wa.
Lasiko ti awọn agbalagba ba n ta ayo ni àwọn ere oṣupa mii maaa n jẹ jade latọdọ awọn ọmọde nita gbangba ki wọn to wọle sun.
Koda ẹ kan le ma mọ ni, oriṣiriṣi isọri ni a pin ere idaraya nilẹ Yoruba si labẹ aburada meji gboogi ti olukọ pe ni "Ojumọmọ" ati "Ere Oṣupa".
- Níwọ̀n ìgbà tó jẹ́ pé owó orí ni wọ́n fi n san owó oṣù àwọn olùkọ́ ilé ìwé náà, àwọn ọmọ lẹ́tọ̀ọ́- IEDPU
- Nkán ìbànújẹ ni bí ọlọ́pàá ṣé tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ OPC mọ́lé nítorí Wakili- Adari OPC
- Àwọn Fulani àti máàlù ń wẹ̀ sínú omí ta ń mu yìí, wọn á tún ní orí wa ti dàrú pé a sọ̀rọ̀ - Olúgbé Yewa ìpínlẹ̀ Ogun