Live: Àwòrán bí ìjọba ìpínlẹ̀ Ekó ṣé ń wó ilé ládùgbóò Lagos Island

Ìgbésẹ̀ ilé wíwó yìí ń wáyé lẹ́yìn ìgbà tí ilé wó pa àwọn èèyàn ládùgbóò Lagos Island nílùú Eko lọ́jọ́ Ìṣẹ́gun.

Aworan bi ijọba Eko ṣe n wo ile ni Lagos Island
Àkọlé àwòrán, Niṣe ni awọn eeyan peju sibi ti ile wiwo naa ti n waye
Aworan bi ijọba Eko ṣe n wo ile ni Lagos Island
Àkọlé àwòrán, O ti rẹ pupọ ninu awọn ile yi sara ti ewu si wa ninu ki awọn eeyan ma gbe inu wọn
Aworan bi ijọba Eko ṣe n wo ile ni Lagos Island
Àkọlé àwòrán, Ninu awọn to n wo iran la ti ri awọn ti wọn wo ile wọn ati awọn miran ti ile wọn sunmọ ibẹ
Aworan bi ijọba Eko ṣe n wo ile ni Lagos Island
Àkọlé àwòrán, Ariwo ti ọpọ aradugbo pa nigba ti ile wo ni iTafaji ni pe awọn alaṣe ko gbe igbesẹ nipa awọn ile to fẹ wo
Aworan bi ijọba Eko ṣe n wo ile ni Lagos Island
Àkọlé àwòrán, Lọjọ keji ijọ ti ile wo ni Ita faji ni wọnwa fagile ile yi fun wiwo
Aworan bi ijọba Eko ṣe n wo ile ni Lagos Island
Àkọlé àwòrán, Aarun oju ni kii ṣe aarun imu pe awọn ile pupọ ladugbo Lagos Island ni ko duro daada
Aworan bi ijọba Eko ṣe n wo ile ni Lagos Island
Àkọlé àwòrán, Aworan bi ijọba Eko ṣe n wo ile ni Lagos Island