You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
2023 Elections: Wo àkójọpọ̀ ìlérí táwọn olùdíje gómìnà mẹ́ta l‘Oyo yóò ṣe fáráàlú
BBC Yoruba seto ipade ita gbangba fawọn oludije gomina nipinlẹ Oyo bi eto idibo gbogbo gboo ti yoo waye lọdun 2023 yii se n sunmọle.
Ọjọru, ọjọ Kọkanla osu Kinni ọdun 2023 yii si ni ipade itagbangba naa ti waye nilu Ibadan nibi tawọn oludije gomina to peju ti sọ ohun ti wọn yoo se fawọn araalu ti wọn ba wọle ibo gomina.
Lara awọn oludije gomina nipinlẹ Oyo to peju sibi itakurọsọ naa la ti ri oludije sipo gomina fẹgbẹ oselu Accord, Oloye Adebayo Adelabu Penkelemesi.
https://www.bbc.com/yoruba/articles/cx83denw1ggo
https://www.bbc.com/yoruba/articles/crg09d0lxeno
https://www.bbc.com/yoruba/articles/cv2638l6jrpo
Bakan naa ni oludije fẹgbẹ oselu Labour, Alhaji Tawfiq Akinwale naa kopa nibi ipade ita gbangba naa.
Oludije fẹgbẹ oselu SDP, Amofin Michael Folorunso Lana naa ko si gbẹyin nibi ifọrọwerọ naa.
Ẹ wa wo ọpọ ohun tawọn oludije gomina ọhun leri leka pe awọn yoo se fawọn araalu ti eyikeyi wọn ba wọle sipo naa.
https://www.bbc.com/yoruba/articles/c2l1pe77l9lo
https://www.bbc.com/yoruba/articles/c87p0zmp5m5o
https://www.bbc.com/yoruba/articles/cer01vx191go
Bakan naa ni wọn mẹnuba idi ti wọn se fi ara wọn silẹ lati sisẹ sin awọn araalu atawọn ọna ti wọn fẹ gbà mu idagbasoke ba ipinlẹ Oyo.
Iroyin ko to afojuba, ẹ wo ẹkunrẹrẹ ohun tawọn oludije sipo gomina naa sọ lasiko eto naa.