You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Children Day 2022: Àwa Obìnrin kìí ṣe àpínmógún, àtẹ̀mẹ́rẹ̀; àwa ní iyọ̀ àti ìrèké ayé
Wo àwọn orisi orukọ to fi pataki ọmọ han ni awujọ.
Oni ni ayajo awọn ewe ni gbogbo agbaye, ki Olodumare da gbogbo ọmọde si ni adura BBC Yoruba.
Awọn akékọọ yii fi ede Yoruba dara.
Se iwo kọ ọmọ rẹ nipa aṣa Yoruba?
Ajoke Omo Opadijo ati Sobakin Waliyah ka ewi ayajọ ewe ati pataki obinrin lawujo.
- Akinwumi Isola dárà nínú ìwé "Nítorí Owó" lórí Akomolede Yoruba
- Kí ni "Future tense" lédè Yorùbá?
- Àwọn Olùkọ́ Akure pegedé lórí ètò Akomolede àti Aṣa lórí BBC Yorùbá
- Agbọ́nmágbọ́ntán, Agọ̀mágọ̀jù, mọ̀ síi nípa àwọn orúkọ Ìjàpá nínú alọ àpagbè Yorùbá
- Awẹ́ Gbólóhùn ni kókó tí à ń gbéyẹ̀wò lónìí lórí ètò Akomolede- Olùkọ Olajide
- Ètò Akọ́mọlédè Yorùbá gbé "Gbólóhùn Yorùbá" yẹ̀wò lọ́sẹ̀ yìí
- Báyìí ni Egúngún àti Orò ṣe jọ bí Ẹ̀ṣà Egúngún nílẹ̀ Yorùba
- Kí lo mọ̀ nípa ìgbeyàwó Àbẹ̀ẹ́lẹ̀, Àṣàǹte, Ọkọ Káalẹ́ àti Gbàmí o ràmí?
Awon akẹkọo to ku fi ijo ibile sami ayeye ọdun ewe 2022 yii pẹlu ayọ.
Bakan naa ni wọn já bàtá ti wọn si fi idunnu wọn han.
Won tun sọ pataki obinrin ninu ile ati pe ki wọn jẹ awokọṣe rere.