Akomolede BBC: Onírurú gbólóhùn léde Yorùbá àti irúfẹ́ gbolóhùn tó wà nínú èdè Yorùbá

Gbogbo ọrọ ti eeyan ba sọ ninu ede Yoruba lo bọ si abẹ gbogbohun, ọkọọkan lo si ni atọka ti a fi n mọ wọn.

Ninu eto "Akọmọlede Yoruba" ti ọtẹ yii Gbolohun ati ipin rẹ ni a gbe yẹwo.