You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ọlatunji, akẹ́kọ̀ọ́gboyè 'graduate' tó ń ta àkàrà 'Ó ta lẹ́nu' nílùú Osogbo
Iṣẹ akara dindin ati tita jẹ ara awọn iṣẹ ti ọjọ ori rẹ pọ julọ ni ilẹ Yoruba, a si lee ka kun ara awọn iṣẹ ti ọpọ maa n foju iṣẹmbaye wo nilẹ Yoruba.
Ni ilu Oṣogbo, ni ipinlẹ Ọṣun lẹkun iwọoorun gusu orilẹede Naijiria arakunrin kan ti orukọ rẹ n jẹ James Ọlatunji dojukọ owo akara dindin ti ọpọ n fi oju iṣẹ obinrin wo lọpọ igba yii to si ti di ilumọọka lori rẹ.
Akẹkọọ jade to gboye lori imọ nipa akoso okoowo, Business administration ni Arakunrin Ọlatunji, o ni lẹyin ikẹkọjade oun, ti oun si wo pe kaka ki oun o maa tọrọ jẹ nitori aisi iṣẹ to wa lode loun fi gbe igba akara dindin ati tita leyi ti oun ko si kabamọ rẹ.
- Ààrẹ tẹ́lẹ̀,GEJ, Atiku Abubakar,Fayemi ati àwọn mìíràn rèé tó péjú síbi ìgbéyàwó Yusuf Buhari
- Ìkáyàsókè ní Ife, Modakẹ̀kẹ̀ lẹ́yìn tàwọn kan pa ọmọ Modakeke márùn ún
- 'Nǹkan ṣe mí', àwọn Fúlàní ìpínlẹ̀ Ondo tí wọ́n pa mọ̀lẹ́bí wọn ní Jos pariwo síta
- Ọlọ́pàá mú afurasí tó pa oniṣowo ẹrọ igbowo POS kan, wọ́n ni àbọ̀dé ìgbẹ́jọ́ Sunday Igboho lọwọ́ tẹ̀ẹ́
- Ọ̀pọ̀ iṣẹ́ Èṣù táwọn èèyàn ń pariwo kò rí bẹ́ẹ̀, aṣe burúkú ṣe rere ni Èṣù
- Àwọn jàǹdùkú sọ àjọ̀dún Amole di 'ọdún olè jíjà' nílùú Akure
- Ọ̀pẹ́lọ̀pẹ́ Olorì Ladun aya Ooni Sijuwade ni mo fi gba òmìnira tí mo sì dúpẹ́ lọ́wọ́ Olorun- Abobaku Ooni Sijuwade
- Ìgbín, iṣu, epo, àádùn, obì, iyọ àti oyin wa lára ohun ti a fi sọ ọmọ tuntun Ọọni Ifẹ lórúkọ!
- Wo ìgbẹ̀yìn àwọn ọlọ̀tẹ̀ Yorùbá tó ran Fulani lọ́wọ́ láti kógun ja ìlú Osogbo
- "Ọ̀pọ̀ ènìyàn tó ń gbé ní Eko, Ibadan, Osogbo ló ti kú..."
- Báwo ní ìpàrójẹ àti ìsúnkì ṣe ń wáyé nínú èdè Yorùbá?
- Olólùfẹ́ mi ṣèèsì fi ọkọ́ gbá mi sí gọ́tà, mo rò pé ọlọ́jọ́ dé ni - Iya Osogbo