You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Oba Olufolarin Ogunsan Alara tí Ilara Epe: Òjò gbọ́dọ̀ rọ̀ lásìkò ọdún Ẹlẹ́gba ni ìlú Epe
Mo gbọdọ sadura fun Kilajolu lẹyin to ba na mi tan lasiko ọdun Ẹ̀bì ni Ilara Ẹpẹ- Kabiesi Alara ti ilu Ilara Ẹpẹ nipinlẹ Eko.
Oba Olufolarin Ogunsanwo to jẹ Alara ti ilu Ilara ni Ẹpẹ ni ipinlẹ Eko ni guusu iwọ oorun Naijiria gba BBC Yoruba lalejo.
Kabiesi ṣalaye itan ilu Ilara ati pataki oye ọba ilu naa lati igba iwaṣẹ.
- Ẹni tó bá ní láàkàyè, a mọ ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn, àwà ti kọ lẹ́tà, èsì t'Ọ́lọ́pàá sì fún wa rèé - Yomi Fabiyi
- Ẹ wo bí Leke Adeboye, àwọn ọ̀dọ́ ìjọ RCCG ṣe gẹ irun wọn láti bú ọlá fún Dare Adeboye tó papòdà
- Egúngún bá òṣèrébìnrin lòpọ̀ nínú eré, àwọn Eléégún yarí
- Báwo ni ìṣẹ̀lẹ̀ ikú Kayode Badru ṣe ṣẹlẹ̀ ní Celestial Church of Christ ni Eko? ẹ wo ohun tí a mọ̀!
- Àwọn Olùkọ́ Yorùbá ní ìpínlẹ̀ Osun ṣe bẹbẹ lórí ètò Akomọlede àti Aṣa lórí BBC
- Amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ Akeredolu tó gbá ìyàwó mi létí ó bá má lọ lọ́fẹ̀ẹ́ - Ọkọ Aláboyún
- Ẹ má kí mi ní ìkíni ọdún, ẹ ṣọdún nilée yín - Ààrẹ Buhari
Oba Alara salaye kikun nipa ọdun Ẹbi ati eegun Kilajolu ti wọn maa n fi kẹyin ọdun naa.
Eegun Kilajolu yii ni yoo kọkọ na Kabiesi Ilarqa lẹgba.
Lẹyin naa ni Kabiesi a ṣadura fun eegun naa ki o to le jade lọ maa na awọn ara ilu Ilara ni Epe ni ọrẹ.
- Wo àwọn ọjà tí o lè fi ṣe pàṣípáàrọ̀ ilé, ẹja àti ǹkan míì ní Nàìjíríà
- Wo orísun agbára tí Sunday Igboho gbójúlé tí ọwọ́ ẹnikẹ́ni kò fi le tẹ̀ ẹ́
- Emmanuel Abina, ọmọ Olùdarí ìjọ GOFAMINT, Elijah Abina jáde láyé lẹ́yìn ikú ìyàwó rẹ̀
- Sultan Sokoto ní káwọn mùsùlùmí wojú ọ̀run fún oṣù tuntun láti parí àwẹ̀
- Báwo ni ìṣẹ̀lẹ̀ ikú Kayode Badru ṣe ṣẹlẹ̀ ní Celestial Church of Christ ni Eko? ẹ wo ohun tí a mọ̀!
Kabiesi Olufolarin Ogunsanwo ni iṣẹ agbẹ ati iṣẹ apẹja ni a mọ awọn eniyan Ilu Ilara Epe mọ lati igab iwaṣẹ ni eyi ti wọn ṣi n ṣe titi di oni.
Oba ni leyin ti oun ba ti ṣadura fun Kilajolu tan ni yoo wa bẹrẹ si ni gabdura fun ilu Epe ati Naijiria lapapọ.