You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Abayọmi Aranmọlatẹ, Dr Laser: Vagino Plasty àti iṣẹ́ abẹ ẹwà Obìnrin ló jẹ mí lógún
Ìdí tí mo fi yan iṣẹ́ abẹ ojú ara obìnrin láàyò rèé- Dr Laser
Vagino Plasty ni iṣẹ abẹ ẹwa obinrin ti ero ko pọ nibẹ rara- Dokita Aranmolate
Ẹwa obinrin ṣe pataki pupọ si wọn.
Dokita to n ṣiṣẹ abẹ lori mimu ẹwa obinrin pọ sii, oniṣegun oyinbo Ayobami Aranmolate salaye awọn igbesẹ to rọ mọo ati idi ti oun fi yan iṣẹ abẹ yii laayo fun BBC Yoruba.
Dr Laser sọ nipa bi iṣẹ abẹ naa ṣe wọn to ati awọn ibi ti oun ti lọ kọ ẹkọ nipa iṣẹ abẹ didi oju ara obinrin to ba fẹ lẹyin ibimọ pada.
O ni ọgbọn isegun yii wa lati ọdọ Olorun ni ati pe ọpọlọ naa kii ṣe ti atọwọda rara.