Oyo Schools: Onírúurú ìbòmú ló gbòde, bí àkẹ́kọ̀ọ́ ṣe wọlé padà

Lọjọ Aje ni awọn akẹkọjade ni ipinlẹ Oyo wọle pada si ile ẹkọ kaakiri ipinlẹ naa.

Awọn akẹkọọ Oyo wọle pada
Àkọlé àwòrán, Awọn ileewe pese ike omi ati ọṣẹ ifọwọ fawọn akẹkọọ
Akẹkọọ Oyo wọle pada
Àkọlé àwòrán, Gbe ori rẹ wa ki n wo bi ara rẹ ti se gbona si
Awọn akẹkọọ Oyo wọle pada
Àkọlé àwòrán, Bi eeyan ba ti kọkọ wọle, ọwọ fifọ jẹ dandan
Awọn akẹkọọ Oyo wọle pada
Àkọlé àwòrán, Awọn akẹkọọ jinasirawọn bi wọn ti se joko ni kilaasi ti wọn si wọ ibomu
Awọn akẹkọọ Oyo wọle pada
Àkọlé àwòrán, Gbagada gbagada lawọn ileewe fi ikede sita lori ilana kikoju arun Covid-19
Awọn akẹkọọ Oyo wọle pada
Àkọlé àwòrán, Awọn akẹkọọ to wa ni ipele ikẹkọjade ti bẹrẹ si ni kẹkọ pada
Awọn akẹkọọ Oyo wọle pada
Àkọlé àwòrán, Lati ẹnu ọna abawọle ni wọn ti n se ayẹwo fun olukọ ati akẹkọọ
Awọn akẹkọọ Oyo wọle pada
Àkọlé àwòrán, Ipinlẹ Oyo ni ipinlẹ akọkọ ti awọn akẹkọọ yoo wọle pada sile ẹkọ ni Naijiria
Awọn akẹkọọ Oyo wọle pada
Àkọlé àwòrán, Pupọ awọn obi lo pese awọn ibomu fawọn ọmọ to pada si ileewe.Ijọba ko pese rẹ fun wọn
Awọn akẹkọọ Oyo wọle pada
Àkọlé àwòrán, Awọn obi tẹle awọn ọmọ wọn de ẹnu ọna ileewe lọjọ kini iwọle pada yi