Abiola Ajimobi: Àwòrán rèé nípa ìgbé ayé Abiola Ajimobi

Eniyan ti itan igbesi aye rẹ tan kalẹ gẹgẹ bi atapata dide ni Abiola Ajimobi jẹ.

Ajimobi ninu aṣọ ibilẹ Yoruba

Oríṣun àwòrán, twitter/Ajimobi

Àkọlé àwòrán, Abiola Ajimobi ninu aṣọ ibilẹ nibi eto kan ni ilu Ibadan
Sẹnetọ Ajimọbi

Oríṣun àwòrán, Twitter/abiola ajimobi

Àkọlé àwòrán, Sẹnetọ Ajimọbi lasiko to n sọrọ lori koko kan to kaa lara nigba to ṣi jẹ Gomina ipinlẹ Oyo
Abiola Ajimobi ati florence aya rẹ

Oríṣun àwòrán, Twitter/abiola ajimobi

Àkọlé àwòrán, Abiola Ajimobi ati Florence aya rẹ ti ọpọ maa n sọ pe Ajimọbi kii ko iyan rẹ kere ni yii lasiko ipolongo fun ẹgbẹ oṣelu onigbalẹ APC
Oloye Ajimobi n jo lọjọ ajọdun aṣa ni ipinlẹ Oyo

Oríṣun àwòrán, Twitter/ajimobi

Àkọlé àwòrán, Oloye Ajimobi n jo lọjọ ajọdun aṣa ni ipinlẹ Oyo
ajimobi pelu aarẹ Muhammadu Buhari

Oríṣun àwòrán, Twitter/abiola ajimobi

Àkọlé àwòrán, Ajimobi pelu Aarẹ Muhammadu Buhari to n tukọ Naijiria labẹ ẹgbẹ oṣelu APC
ajimobi pelu gomina ipinlẹ Ekiti tẹlẹ, Ayọdele Fayose

Oríṣun àwòrán, Twitter/ajimobi

Àkọlé àwòrán, Ajimobi pelu gomina ipinlẹ Ekiti tẹlẹ, Ayọdele Fayose, ọrẹ ṣiṣe ko kan iyatọ ninu ẹgbẹ oṣelu ti koowa wa!
ajimobi pelu Emir tilu tẹlẹ, Sanusi Lamido

Oríṣun àwòrán, Twitter/ajimobi

Àkọlé àwòrán, Ajimobi pelu Emir tilu Kano tẹlẹ, Sanusi Lamido Sanusi lasiko ti wọn jọ n fi ọrọ jomitooro ọrọ
sẹnetọ ajimọbi pẹlu awọn agba oye ilẹ Ibadan to gbe soke di ọba

Oríṣun àwòrán, Twitter/ajimobi

Àkọlé àwòrán, Kò ṣẹlẹ rí nilẹ Ibadan, Ajimọbi pẹlu awọn agba oye ilẹ Ibadan to gbe soke di Ọba lọjọ kan ṣoṣo
ajimobi pelu Alaafin Oyo

Oríṣun àwòrán, Twitter/ajimobi

Àkọlé àwòrán, Ajimobi pelu Alaafin Oyo, iku baba yeye Adeyemi kẹta lasiko ti Ajimọbi fi n tukọ ipinlẹ Oyo gẹgẹ bii gomina
Ajimobi pẹlu gomina tẹlẹ nipinlẹ Oyo, Alao akala

Oríṣun àwòrán, twitter/Ajimobi

Àkọlé àwòrán, Ọrẹ la o maa ṣe! Sẹnetọ Ajimobi pẹlu gomina tẹlẹ nipinlẹ Oyo, Alao Akala lasiko ti wọn jọ n ṣe awada
sẹnetọ ajimọbi n gbe opa aṣẹ fun ọkan lara awọn agba oye ilẹ Ibadan to gbe soke di ọba

Oríṣun àwòrán, Twitter/ajimobi

Àkọlé àwòrán, Sẹnetọ Ajimọbi lasiko to n gbe opa aṣẹ fun ọkan lara awọn agba oye mọkanlelogun ilẹ Ibadan to gbe soke di Ọba
Abiola Ajimobi pẹlu aṣiwaju Bola Ahmed Tinubu

Oríṣun àwòrán, Twitter/abiola ajimobi

Àkọlé àwòrán, Abiola Ajimobi pẹlu aṣiwaju Bola Ahmed Tinubu, agba ẹgbẹ oṣelu APC. ọrun ma kanju ni awọn agba Yoruba maa n wi! Ilẹ n jẹ eeyan
Senato Ajimobi pẹlu gomina Kayode Fayemi ti ipinlẹ Ekiti

Oríṣun àwòrán, Twitter/abiola ajimobi

Àkọlé àwòrán, Senato Ajimobi pẹlu gomina Kayode Fayemi ti ipinlẹ Ekiti, ọmọ iya ẹgbẹ oṣelu APc ni awa mejeeji
Sẹnetọ Ajimọbi pẹlu awọn eekan agbabọọlu orilẹede Naijiria nigbakanri , Ikẹ Sorunmu, Mutiu Adepoju Yobo Joseph, Emmanuel Amokachi pẹlu minisita fere idaraya,

Oríṣun àwòrán, Twitter/ajimobi

Àkọlé àwòrán, Sẹnetọ Ajimọbi pẹlu awọn eekan agbabọọlu orilẹ-ede Naijiria nigba kan ri, Ikẹ Sorunmu, Mutiu Adepoju Yobo Joseph, Emmanuel Amokachi pẹlu minisita fun ere idaraya,
Abiola Ajimobi, Aarẹ Muhammadu Buhari ati Adams Oshiomole

Oríṣun àwòrán, Twitter/ajimobi

Àkọlé àwòrán, Abiola Ajimobi, Aarẹ Muhammadu Buhari ati Adams Oshiomole ti wọn ṣẹṣẹ yọ kuro nipo alaga ẹgbẹ oṣelu APC. Iku a pa ẹni a n pè, iku a tun pa ẹni to n pe ni! Alumuntu ti kii jẹ ki araye dagbere fun ara pe asiko ti to!
Ajimobi pẹlu alaga ẹgbẹ oselu APC ti ile ẹjọ ṣẹṣẹ rọ loye, Adams Oshiomole ati igbakeji aarẹ Yẹmi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, Twitter/ajimobi

Àkọlé àwòrán, Ajimobi pẹlu alaga ẹgbẹ oselu APC ti ile ẹjọ ṣẹṣẹ rọ loye, Adams Oshiomole ati igbakeji aarẹ Yẹmi Osinbajo
Ajimobi pẹlu GOMINA SEYI MAKINDE

Oríṣun àwòrán, Twitter/abiola ajimobi

Àkọlé àwòrán, Ajimobi pẹlu Seyi Makinde to n tukọ ipinlẹ Oyo bayii labẹ akoso ẹgbẹ oṣelu PDP; ọrọ oṣelu ọtọ, ọrọ itẹsiwaju ipinlẹ Oyo ati idagbasoke awọn eeyan ibẹ ọtọ! Eyi ko si nii fi ṣe irufẹ ẹgbẹ oṣelu to ba wa ni ijọba bikoṣe ka ni ifọwọsowọpọ lagba