Coronavirus: BBC News Yorùbá ní kí ẹ dúró nílé bí ẹ kò bá ní ìdí láti jáde

Lasiko ti a wa yii, asiko ẹlẹgẹ ati ikiyesara gidi ni.

Bi a ba tẹle awọn imọran gbogbo tawọn onimọ n fi sita a o laa ja.

Idunnu wa ni ileeṣẹ BBC News kaakiri agbaye ni pe ki a ka iye awọn eeyan to laa ja lẹyin ọwọja ajakalẹ arun yii, ki gbogbo ẹyin ololufẹ wa si dahun orukọ yin.

Ẹ wo fidio yii gẹgẹ bi ẹbun kekere ti a ni fun un yin.