Human trafficking in Libya: Ẹsẹ̀ bàtà àti èso kukumba ni wọ́n fi ń já àbálé àwọn ọmọ Nàìjíríà ní Libya-Yetunde, arìnrìnàjò sí Libya

Ohun taa jẹ, taa mu, taa fi r'ile aye gbe lo mu arabinrin yii kuro ni Naijiria lọ orilẹede Libya.

lootọ kii ṣe orilẹede Libya ni wọn sọ fun un pe yoo lọ tẹlẹ, nigba ti ọrọ yoo fi foju han sii, oju ọna Libya lo ti ba ara rẹ.

ohun ti oju rẹ ri lọna nigba to n lọ, a ti mu wa fun iran yin ni abala akọkọ, abala ekeji ree nibi ti arabinrin Yetunde Abrahams ti sọ ohun ti oju rẹ ri ni Libya ati bi irinajo rẹ lati pada si orilẹede NAijiria ṣe jẹ.