You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Oman Slave: Ó pe mi kí n máa mu Gari ní Nàìjíríà ju ìlú yẹn lọ o
Ohun taa jẹ, taa mu, taa fi r'ile aye gbe lo mu arabinrin yii ti a ko le fi oju rẹ han kuro ni Naijiria lọ gba iṣẹ ni orilẹede Oman.
Arabinrin yii s fun BBC pe jẹjẹ loun wa nilu wọn ti wọn sọ fun un pe iṣẹ wa ni orilẹede kan ti wọn yoo ti maa san owo to to igba miliọnu naira fun un.
"Bi kii ba ti ṣe iṣẹ aṣẹwo, o dara". Ni arabinrin yii fesi fun awọn aburo rẹ to ba a wa iṣẹ. O de 'bẹ tan lorin ba yipada.
- Ṣé o mọ̀ pé o leè rí omira abẹ́ obìnrin rà tàbi fi tìrẹ silẹ̀ fún títà?
- 'Ojú mi rí tóó, àwọn ìyàwó kìí ṣiṣẹ́, ọkọ àtàwa ọmọ-ọ̀dọ̀ laláṣekú lórílẹ̀èdè Oman'
- 'Iṣẹ aṣẹwo ni wọn fi mi ṣe ni Moscow'
- Òwò ẹrú pé irinwó ọdún tó bẹ̀rẹ̀, àwọn Amẹrika tó jẹ́ dúdú wá sí Afirika láti bẹ ilé wò
- Mo máa ń dédé ṣubú lulẹ̀, tẹ́ẹ bá fi ọwọ kàn mí lásán, kódà lójú ọ̀nà márosẹ̀ - Fatimah Aderounmu
- 'Èmi ọmọ Ikorodu ọ̀ga, ọmọ aṣalẹ̀ jẹ́jẹ! Wo bí àwọn ọmọdé tó "tuush" yìí ṣe ń fi oríkì Yorùbá dábíra