You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Yoruba Films: Òṣèrè tíátà Muideen Oladapo gbàràdá lórí ètò 'Ṣé o láyà?'
Oṣere tiata Yoruba, Muideen Oladapo fihan lori eto BBC Yoruba, ''Ṣe o Laya'' pe oun laya gbangba.
Bi o ti n dahun awọn ibeere ti wọn bi i, bẹẹ naa lo n ṣe atupalẹ idahun rẹ si awọn ibeere naa.
Muideen fihan pe oun gbọ ede Yoruba daadaa gẹgẹ bi oṣere ere tiata Yoruba.
- Ìbànújẹ̀ ní ọdún tuntun, àwọn ènìyàn tẹ ara wọn pa!
- Ènìyàn márùn-ún pàdánù ẹ̀mí wọn níbi ayẹyẹ ọdún tuntun ní Oyo
- Ìtàn Manigbagbe: Àwọn àjakalẹ-àrun to ti wáyé rí ṣáájú Coronavirus
- Àánú táwọn èèyàn yóò fi máa sọ wí pé ọ̀nà wo lo gbà ni yóò wọlé fún ọ ní ọdún 2023
- Ẹ máa ṣe àmín bí Adewale Alebiosu, àgbà òṣèré tíátà, ṣe ń gbàdúrà ọdún túntún fún yín
- Èrè tó pọ̀ ni gbogbo Oníṣòwò máa jẹ ní 2023- Imam Sabit Olagoke