You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
International Women's day 2020: Àwọn obìnrin tọ́kasí pàtàkì ìbáraẹnidọ́gba láárin ọmọnìyàn
Ọjọ kẹjọ ọdọọdun ni ayajọ awọn obinrin lagbaye nibi ti gbogbo agbaye ti n kọju si awọn obirin lati yombo awọn iṣẹ takuntakun ti wọn gbe ṣe lai nọọni oniruuru ipenija, ẹdun ọkan ati ilakaka wọn fun aṣeyọri gbogbo laarin kaakiri agbaye.
- 'Ojú mi rí tóó, àwọn ìyàwó kìí ṣiṣẹ́, ọkọ àtàwa ọmọ-ọ̀dọ̀ laláṣekú lórílẹ̀èdè Oman'
- Kí ló le è mú kí ìlú kan ó já ọmọge mẹ́rin sí ìhòhò?
- Mò ń tọ̀ s'ára ni mo fi gba ara à mi l'óko ẹrú ní Oman
- Obìnrin tó ń ṣiṣẹ́ ẹrú ní orílẹ̀èdè Oman tó bá fẹ́ ní òmìnira, gbọdọ̀ bá ọ̀gá rẹ̀ ṣùn - Obìnrin méjì tó ti Oman dé
- Kò dín ní ọkùnrin márùndínlógún tó ń bá mi lò lójúmọ́
- Ẹyin ni wọ́n fi n gba ìbále ẹlòmiran lára wa ki a to lọ pàde àwọn oníbara
Ẹtọ awọn obinrin pẹlu idọgba pẹlawọn ọkunrin lo gbode gẹgẹ bii ohun ojutaye lasiko ajọyọ ayajọ obinrin lagbaye ti ọdun yii.
Akọmọna ayajọ naa fun ọdun yii ni "ajafẹtọ ibaradọgba ni mi: mimu ẹtọ awọn obinrin ṣẹ."
- Kásà, ewé sunko fún àgbà òṣèré tíátà, Fádèyí Olóró
- Làá hàn mí dé, ètò tó ń ṣàlàyé ohun tó yẹ ká ṣe láti dènà àrùn Coronavirus
- 'Obinrin lo mu mi fẹran orin kikọ'
- Fọlọrunṣọ Alakija: Obinrin nilo imọ
- Angelique kidjo pe fun anfani f'awọn obinrin
- Mo fẹ́ di obinrin to dára júlọ lágbàyé-Bobrisky
- Kíni ìdí ti wọn fi ń lọ ọmú obinrin
Ninu ọrọ tiwọn, ajọ iṣọkan agbaye rọ awọn eeyan gbogbo lati ji giri gbogun ti awọn ipenija aidọgba laarin ẹya ẹda gbogbo.
Ninu fidio BBC News Yoruba fun ayajọ yii, awọn obinrin ni oriṣiriṣi ilana iṣẹ aje gbogbo sọrọ lori ipenija ti wọn n dojukọ; paap julọ laarin awọn ọkunrin lẹnu iṣẹ aje gbogbo.