Obinrin lo mu mi fẹran orin kikọ - Patoranking

Akọrin taka-sufee, Patoraking sọ̀ wi pe ifẹ obinrin lo mu oun fẹran orin kikọ.