Ọkọ̀ agbépo kan ti yi dànù ni Agege nípinlẹ̀ Eko
Ajọ to n risi iṣẹlẹ pajawiri LASEMA atawọn panapana ti de sibẹ bayii ti wọn si ti n ko awọn eeyan kuro ni agbegbe naa.