Faṣola ni àwọn ọ̀nà Nàìjíríà kò bàjẹ́ tọ bí wọ́n ṣe ń pariwo

Àwọn ènìyàn Nàìjíríà fi fọ́tò àwọn ọ̀nà wọn tó ti bàjẹ́ ránṣẹ́ sí BBC ki Faṣọla lè àtúnṣe ṣáájú ọdún Kérésì síi bó ṣe sọ.