Faṣola ni àwọn ọ̀nà Nàìjíríà kò bàjẹ́ tọ bí wọ́n ṣe ń pariwo

Àwọn ènìyàn Nàìjíríà fi fọ́tò àwọn ọ̀nà wọn tó ti bàjẹ́ ránṣẹ́ sí BBC ki Faṣọla lè àtúnṣe ṣáájú ọdún Kérésì síi bó ṣe sọ.

ona
Àkọlé àwòrán, Eyi ni oju ọna Ekoro road ni Abule egba ni ipinlẹ Eko, ẹnikan lo fi ranṣẹ soju opo BBC ki fasola le tete rii.
ona
Àkọlé àwòrán, Eyi ni oju ọna Agbado si Ijokoo nipinlẹ Ogun bi wọn ṣe fi ranṣẹ si BBC
ona
Àkọlé àwòrán, Asolo si Isawo ni opopona yii ni Agric ni ikorodu ni Naijiria
ona
Àkọlé àwòrán, Opopona Gafaru ni Ikọtun ni ipinlẹ Eko ti Faṣọla ti ṣe gomina ọdun mẹjọ ni yii
ona
Àkọlé àwòrán, Eyi ni koto nla ni opopona Akobọ si oju irin ni ilu Ibadan ni ipinlẹ Oyo ti wọn fi ranṣẹ si minista ọrọ iṣẹ akanṣe
ona
Àkọlé àwòrán, Oju ọna Moniya si Isẹyin to yẹ ko jẹ marosẹ Oyo si Isẹyin ni yii ti ẹnikan fi ranṣẹ si BBC
ona
Àkọlé àwòrán, Roundabout Ogbomoṣọ lọna fasiti Ladoke Akintola ni Ogbomọṣọ ni yii
ona
Àkọlé àwòrán, Opopona B Division ni Suleja ni ipinle Niger ni yii ti eeyan ko le fẹsẹ rin lairi ka to sọ ọkọ
ona
Àkọlé àwòrán, Iyana Ejigbo nipinlẹ Eko ni yii ti agbara ojo ti gba opopona mọ awọn eeyan lọwọ
ona
Àkọlé àwòrán, Opopona Ikorodu si Imọta ni yii ti ẹnikan fi ranṣẹ si BBC ki minista le fi kun ibi ti iṣẹ a ti waye laipẹ.
ona
Àkọlé àwòrán, Agbegbe Agọ Ijeṣha ni ilu Abeokuta nipinlẹ Ogun niyii ti ẹnikan fi ṣọwṣo si BBC
ona
Àkọlé àwòrán, Ọjọta ni yii ni ipinlẹ Eko ti ẹnikan fi ranṣẹ si BBC ki Faṣọla le ṣi mọ ibi ti wọn maa tunṣe
ona
Àkọlé àwòrán, Adugbo Imẹkọ ni yii ti ọrọ opopona naa kan awọn agbaagba lati wa nkan ṣe sii bayii