You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Primate Ayodele: Àwọn pásítọ̀ tó ń lo bàálù pẹ̀lú èrò rẹpẹtẹ ń tan aráàlú jẹ ni
Oluṣọaguntan agba Ayodele ni oludasilẹ ijọ INRI Evangelical Spiritual Church ti a si mọ ọ fun ọpọlọpọ asọtẹlẹ lorilẹede Naijiria.
Bakan naa o ti di gbajugbaja lori ayelujara fun oniruuru ọrọ to ma n suyọ latari awọn asọtẹlẹ rẹ.
Primate Ayodele gẹgẹ bi gbogbo eeyan ṣe maa n pe ni awọn iran mii ti ojiṣẹ Ọlọrun ba sọ, bo ṣe ri kọ ni ẹlomiran ṣe ma n tumọ rẹ lo fi ma n da bii pe ko wa si imuṣẹ.
- Lailai Apostle Suleiman kò lè gba onídùúró mí! - Sowore
- 'Ọjà tí wọ́n ti ń ká owó ni ìlú Eko jẹ́ fáwọn onílé báyìí'
- Yinka Ayefele ṣe ìkọ́mọ ìbẹta rẹ̀, ọ̀nà ò gbẹsẹ̀
- Àṣírí ilé ìmúni nígbèkùn míràn tú síta ní Ibadan
- 'Màálù tó bá tàsẹ̀ àgẹ̀rẹ̀ níwájú ilé mi, ó dẹran àsun!"
- Wíwó laá wó àwọn ilé ìkẹ́rùpamọ̀sí tó wà láwọn ibodè wa
Ṣugbọn o ni gbogbo asọtẹlẹ ti oun ma n sọ maa wa ni akọsilẹ.
Bakan naa o jẹ ko di mimọ pe ijọba gan ko ṣe e dara tori bo ba ṣe nkan to nii ṣe pẹlu aṣa ni wọn lee kede isinmi ṣugbọn nkan ti Ọlọrun ni ijọba ko ki n fẹ kede isinmi fun.
O ni awọn pasitọ to n lọ tẹnu bọlẹ kiri lọdọ ijọba tabi oloṣelu n wa ohun ti wọn a jẹ kiri ni amọ oun o ki n ṣe eeyan bẹẹ́.