BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
LagosRainDamage: Òjò àrọ̀rọ̀ọ̀dá òní ṣọṣẹ́ tó pọ̀ ni Lekki nipinlẹ Eko
12 Ọ̀wàrà 2019
Ẹ wo ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn òjò àrọ̀rọ̀ọ̀dá láàrọ yii ni Lekki nipinlẹ Eko!
Àkọlé àwòrán,
Adugbo Muritala Eletu lomi ti kun gbogbo adugbo ni Lekki ni ipinlẹ Eko bayii.
Àkọlé àwòrán,
Opopona Marosẹ ni Lekki ti wọn gba pe o jẹ adugbo awọn to ri jajẹ diẹ ni omi ti ya wọ bayii, kini ipin awọn adugbo mii a jẹ?
Àkọlé àwòrán,
Adugbo Razak Eletu ni Osapa Garden Estate ni Lekki ni agbara ojo ti gba opopona mọ awọn eeyan lọwọ yii
Àkọlé àwòrán,
Omi ti n fẹ yale ki agbara ya ṣọọbu mọ awọn ara Eko lọwọ bayii bẹẹ gomina ni o di oṣu kọkanla ki iṣẹ atunṣe opopona to bẹrẹ
Àkọlé àwòrán,
Adugbo Razak Eletu ni Osapa Garden Estate ni Lekki lo sọ gbogbo olugbe ibẹ di konile-o-gbele lasiko yii
Àkọlé àwòrán,
Awọn igbesẹ wo ni ẹyin to pe ijọba yẹ ko gbe lati fopin si iru omi ya titi to n ṣẹlẹ bayii ni Lekki?
Àkọlé àwòrán,
Adugbo Bamidele Eletu niyii ni Lekki ti awọn ike ati oriṣii nkan ti n luwẹ lodo
Àkọlé àwòrán,
Agbara ojo ree niyara ẹni kan to n gbe ni Lekki nibi ti omi ti ya wọle ti ọpọ ohuneelo ile si ti bajẹ!
Àkọlé àwòrán,
Abawọle inu ile kan ni adugbo Bamidele ni Lekki ree ti omi ti di awọn olugbe mọle ni Osapa Garden Estate ni ipinlẹ Eko
Àkọlé àwòrán,
Herbert Macauly way rèé ti ko sẹni to le foju ri opopona mọ
You might also like:
news
|
sport
|
weather
|
worklife
|
travel
|
future
|
culture
|
world
|
business
|
technology