Onísòwòo Nàìjíríà àti South Africa ń ṣe ìpàdé nígbà tí Ààrẹ Buhari lọ sí South Africagbà

Ẹ wo bí ìpàdé àwọn oníṣòwòo Nàijíríà àti South Africa ṣe ń lọ lórílẹ̀èdè Gúúsù Afrika naa nígbà tí Ààrẹ Buhari ń ṣe àbẹ̀wò síbẹ̀.

Abilekọ Lovina Kayode láti àjọ tó ń rí sí ìdàgbà s'ókè ìdókòwò Nàìjíríà ń s'ọ̀rọ̀ nípa ìdókòwò ní Nàìjíríà
Àkọlé àwòrán, Abílékọ Lovina Kayode láti àjọ tó ń rí sí ìdàgbà s'ókè ìdókòwò Nàìjíríà ń s'ọ̀rọ̀ nípa ìdókòwò ní Nàìjíríà
Ambassador Sadick Jaffer, adarí ńlá láti Àjọ òwò àti ilé iṣẹ́ẹ South Africa
Àkọlé àwòrán, Ambassador Sadick Jaffer, adarí ńlá láti Àjọ òwò àti ilé iṣẹ́ẹ South Africa
Àwọn onísòwò láti orílẹ̀èdè méjéjì ń gbọ́ ọ̀rọ̀ nípa àǹfàní tó wà níbi òwò ní orílẹ̀èdè méjéjì.
Àkọlé àwòrán, Àwọn onísòwò láti orílẹ̀èdè méjéjì ń gbọ́ ọ̀rọ̀ nípa àǹfàní tó wà níbi òwò ní orílẹ̀èdè méjéjì.
Láìpẹ́ yìí ni ìbáṣe láàrin Nàìjíríà àti South Afrika bàjẹ́ látàri bí wọ́n ń ṣe ń kọlu àwọn ọmọ Nàìjíríà ní orílẹ̀èdè náà
Àkọlé àwòrán, Láìpẹ́ yìí ni ìbáṣe láàrin Nàìjíríà àti South Afrika bàjẹ́ látàri bí wọ́n ń ṣe ń kọlu àwọn ọmọ Nàìjíríà ní orílẹ̀èdè náà, Onísòwòo Nàìjíríà àti South Africa ń ṣe ìpàdé ní South Africa
Oríẹ̀èdè méjéjì ń gbìnyànjú láti gbàgbé ọ̀rọ̀ ìjà ẹlẹ́yàmẹyà tó ṣẹlẹ̀ láàrin wọn láìpẹ́ yìí
Àkọlé àwòrán, Oríẹ̀èdè méjéjì ń gbìnyànjú láti gbàgbé ọ̀rọ̀ ìjà ẹlẹ́yàmẹyà tó ṣẹlẹ̀ láàrin wọn láìpẹ́ yìí
Ààrẹ Muhammadu Buhari ń ṣe àbẹ̀wò sí orílẹ̀èdè náà l'Ọ́jbọ àti ọjọ́ Ẹtì
Àkọlé àwòrán, Ààrẹ Muhammadu Buhari ń ṣe àbẹ̀wò sí orílẹ̀èdè náà l'Ọ́jbọ àti ọjọ́ Ẹtì
Abílékọ Lovina Kayode láti àjọ tó ń rí sí ìdàgbà s'ókè ìdókòwò Nàìjíríà ń s'ọ̀rọ̀ nípa ìdókòwò ní Nàìjíríà
Àkọlé àwòrán, Abílékọ Lovina Kayode láti àjọ tó ń rí sí ìdàgbà s'ókè ìdókòwò Nàìjíríà ń s'ọ̀rọ̀ nípa ìdókòwò ní Nàìjíríà
eniyan

Oríṣun àwòrán, @Govt ZA

Àkọlé àwòrán, Awọn eniyan South Africa n duro ki Arẹ Buhari
buhari

Oríṣun àwòrán, @Govt ZA

Àkọlé àwòrán, Aarẹ Buhari n ki awọn minista Ramaphosa ni Pretoria ni South Africa
Buhari

Oríṣun àwòrán, @GovtZA

Àkọlé àwòrán, Aarẹ Buhari n ki awọn ti Aarẹ Ramaphosa South Africa jọ n ṣejọba