BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ọlọ́jọ́ festival: Káríayé làwọn èèyàn ti wá gán-ní ọdún Ọlọ́jọ́ ní Ilé-ifẹ̀
28 Owewe 2019
Ọdun ọlọjọ jẹ ajọyọ ojumọ akọkọ lorilẹ aye.
Àkọlé àwòrán,
Ọọni ile ife n rin laarin ọpọ ero pẹlu Ade Are lori
Àkọlé àwòrán,
Ọọni ile ife n rin laarin ọpọ ero pẹlu Ade Are lori
Àkọlé àwòrán,
Ọdun ọlọjọ nilu Ifẹ
Àkọlé àwòrán,
Ọọni ile ife n rin laarin ọpọ ero pẹlu Ade Are lori
Àkọlé àwòrán,
Ọọni ile ife n rin laarin ọpọ ero pẹlu Ade Are lori
Àkọlé àwòrán,
Ọọni ile ife n rin laarin ọpọ ero pẹlu Ade Are lori
Àkọlé àwòrán,
Ọọni ile ife n rin laarin ọpọ ero pẹlu Ade Are lori
Àkọlé àwòrán,
Ọọni ile ife n rin laarin ọpọ ero pẹlu Ade Are lori
Àkọlé àwòrán,
Ọọni ile ife n rin laarin ọpọ ero pẹlu Ade Are lori
Àkọlé àwòrán,
Ọọni ile ife n rin laarin ọpọ ero pẹlu Ade Are lori
Àkọlé àwòrán,
Ọọni ile ife n rin laarin ọpọ ero pẹlu Ade Are lori
Àkọlé àwòrán,
Eto ti n lọ ni pẹrẹu nibi ajọdun Ọlọjọ ni ile ifẹ
Àkọlé àwòrán,
Ọdun Ọlọjọ jẹ ọdun akọkọ ninu itan Yoruba.
Àkọlé àwòrán,
Kaakiri agbaye ni awọn eeyan ti maa n wa lati wa ṣe ọdun yii
Àkọlé àwòrán,
Ọdun Ọlọjọ jẹ ayajọ ojumọ akọkọ ni orilẹ aye.
Àkọlé àwòrán,
Gbogbo ọmọ ile Ifẹ ni wọn maa n wale wa ṣe ọdun yii
Àkọlé àwòrán,
Oniruuru ayẹyẹ ni o maa n waye lasiko ọdun yii
Àkọlé àwòrán,
Lasiko ọdun yii, Kabiyesi Ọọni maa n gba adura latọwọ awọn oloye gbogbo yoo si tun ṣe adura fun gbogbo eeyan
Àkọlé àwòrán,
Awọn lọbalọba pẹlu peju sibi ayajọ naa
Àkọlé àwòrán,
Ọdun ọlọjọ nilu Ileefẹ
Àkọlé àwòrán,
Ọdun ọlọjọ nilu Ileefẹ
Àkọlé àwòrán,
Ọdun ọlọjọ nilu Ileefẹ
Àkọlé àwòrán,
Ọdun ọlọjọ nilu Ileefẹ
Àkọlé àwòrán,
Ọdun ọlọjọ nilu Ileefẹ
Àkọlé àwòrán,
Ọọni ile ife n rin laarin ọpọ ero pẹlu Ade Are lori
Àkọlé àwòrán,
Ọdun ọlọjọ nilu Ileefẹ
Àkọlé àwòrán,
Ọdun ọlọjọ nilu Ileefẹ
Móríwú
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
01:36
Fídíò,
Ìwádìí BBC tú àṣírí àwọn tó ń fi ajá tó ṣèse lú jìbìtì gbowó lórí ayélujára
, Duration1,36
03:25
Fídíò,
Wọ́n pe pásítọ̀ kó wá ṣe ìṣọ́ òru ní ṣọ́ọ̀ṣì ni káwọn agbébọ̀n tó yìnbọn paá – Aráàlú sọ̀rọ̀ lórí ìkọlú àwọn agbébọn sí ṣọ́ọ̀ṣì kan l'Ekiti
, Duration3,25
01:13
Fídíò,
Ìdí rèé tí ọ̀dà tí o fi ń kun irun rẹ sí àwọ̀ mìràn ṣe lè fa jẹjẹrẹ ọyàn fún ọ
, Duration1,13
03:19
Fídíò,
"Igede Ekiti ni ilé Osun, omi rẹ̀ sàn dé Osogbo ni, ohun tó mú u yíra padà kò di odò ńlá rèé"
, Duration3,19
01:59
Fídíò,
Ǹ jẹ́ ẹ mọ nípa Ọdún Ẹlẹ́gba Èjìwà l‘Eko níbi tí takọ-tabo kìí wọ aṣọ tàbí bàtà?
, Duration1,59
01:41
Fídíò,
Ìjà ìlú wa là ń gbè, a gbà, tí ẹ bá ní à ń ṣe ìwà ipá sáwọn àjèjì - Àwọn ọmọ South Africa ṣe ìwọ́de
, Duration1,41
04:52
Fídíò,
"Ìdí rèé tí mo ṣe fi àkàrà òyìnbó mọ ṣọ́ọ̀ṣì kàtídírà ńlá, èyí tó jẹ́ ìyanu fún ọ̀pọ̀ èèyàn"
, Duration4,52
02:10
Fídíò,
Ohun tí a mọ̀ rèé lórí ohun tó fa ìkọlù ikọ̀ afẹ̀jẹ̀wẹ̀ nílẹ̀ Mali èyí tó mú ọ̀pọ̀ ẹ̀mí lọ
, Duration2,10
02:01
Fídíò,
Lisabi 2026: Wo bí àwọn ọmọ Abeokuta ṣe dábírà níbi ayẹyẹ ìrántí akọni wọn
, Duration2,01
01:21
Fídíò,
Tí àtọ̀ ọkùnrin kò bá lágbára tó, àwọn ìṣòro tó lè dá sílẹ̀ fún obìnrin rèé
, Duration1,21
05:34
Fídíò,
Akanmu Epo Akara, bíríkìlà tó gbé orin Àwúrebe ga, tí ọmọ rẹ̀ tún tẹ́wọ́ gbàá
, Duration5,34
02:48
Fídíò,
Awodi: Òrìṣà òjò tí abọrẹ̀ rẹ̀ kò gbọdọ̀ ru ẹrù tàbí ṣe aṣemáṣe pẹ̀lú obìnrin
, Duration2,48
03:51
Fídíò,
Wọ́n kó Rasheed mérò níbi ìwọ́de EndSARS lọ́dún 2020, ọdún mẹ́fà ló lò lẹ́wọ̀n
, Duration3,51
More:
News
•
Sport
•
Weather
•
Worklife
•
Travel
•
Future
•
Culture
•
World
•
Business
•
Technology
•
Science_and_environment
•
Entertainment_and_arts