Nigeria Population: Báwọn ọmọ Nàíjíríà ṣe ń pọ̀ si jẹ́ ìpèníjà fún Buhari
Nibayii ti aarẹ Muhammadu Buhari ti sebura fun saa keji lori aleefa gẹgẹ bii aarẹ orilẹede Naijiria, ọpọ awọn ọmọ orilẹede naa lo ti n fi igbe bọnu pe awọn ko ri isẹ se.
Lasiko ti wọ̀n n ba akọroyin BBC sọrọ, ọpọ eeyan lo tun ni awọn ni iwe ẹri to yẹ, amọ ti isẹ oojọ di isoro.
Fun apẹẹrẹ, ni ipinlẹ Rivers, ti epo rọbi sodo si julọ lorilẹede Naijiria, ọpọ olugbe ipinlẹ naa lo ni ko si owo lọwọ, ko si isẹ lati se, ti ebi si n pa awọn.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Èèyàn 5 farapa, ọ̀pọ̀ ọkọ̀ jóná nínú ìjàmbá iná márosẹ̀ Ibadan sí Eko
- Dúkìá mi ò lé kan o, mo ti dá fọ́ọ̀mù padà bó ṣe wà tẹ́lẹ̀ - Buhari, Osinbajo
- Boko Haram àti àwọn Fulani daran daran jẹ́ ọgbọ́n áti sọ Nàíjíríà di ìlú mùsùlùmí - Wale Oke
- 'A sọ fún ọlọ́kadà pé omi kún, omi kún, ṣùgbọ́n ó kọ etí ikún' #Adewura
Koda, wọn ni awọn ni iya ati baba to yẹ ki awọn maa fun lowo, amọ ti ebi n pa wọn, nitori airi isẹ se awọn.
Amọ awọn miran tiẹ fikun pe, o lee jẹ iṣẹ kan pere ni awọn n ri se ni odidi ọṣẹ kan.
Ni bayii ti aarẹ Muhammadu Buhari si ti bẹrẹ saa keji rẹ lori aleefa