Swearing in 2019: Àga, àsìá, àtìbàbà àti ẹní àtẹ́ẹ̀ká ti wà nílẹ̀ fún ìbúra

Ọjọru ọjọ Kọkandinlọgbọn o'su Karun ọdun 2019 ni ayẹyẹ ibura yoo waye Fun aarẹ Muhammadu Buhari ni ilu Abuja.

Ibudo ti eto ibura yoo ti waye

Oríṣun àwòrán, Musictori

Àkọlé àwòrán, Ori pepele yii ni akọsilẹ itan miran yoo tun ti waye nigba ti Buhari ba ṣe ibura fun saa keji lori rẹ
Ibudo ti eto ibura yoo ti waye

Oríṣun àwòrán, Musictori

Àkọlé àwòrán, Ori pẹpẹ yii ni eto ibura yoo ti waye fun aarẹ Buhari lọla
Aga ijoko ọlọla

Oríṣun àwòrán, Musictori

Àkọlé àwòrán, Alaga ọlọla ree fun awọn alejo pataki ti yoo peju sibi ibura aarẹ Muhammadu Buhari
Ẹni atẹẹka

Oríṣun àwòrán, Musictori

Àkọlé àwòrán, Ẹni atẹẹka to wọle sibi gbagede ibura ree ti aarẹ atawọn eeyan pataki miran yoo gba kọja
Ibudo ti eto ibura yoo ti waye

Oríṣun àwòrán, Musictori

Àkọlé àwòrán, Awọn ohun ase ibudo lọṣọ ti wa nikalẹ nibi ibudo ayẹyẹ ibura
Awọn oṣiṣẹ agbofinro to wa nikalẹ ni ibudo ibura ni ilu Abuja

Oríṣun àwòrán, Musictori

Àkọlé àwòrán, Ẹni ti yoo jẹun gbọin-gbọin yoo tilẹkun gbọin-gbọin lọrọ ipese eto aabo ni ibudo ibura ti yoo waye lọla
Oju popo kan nilu Abuja

Oríṣun àwòrán, Musictori

Àkọlé àwòrán, Ilu Abuja ti dun wo pẹlu oniruuru aramọnda ọṣọ to gba oju popo kan