World Day for Cultural Diversity: Bí àwọn òṣìṣẹ́ Ìpínlẹ̀ Oyo ṣe f'aṣọ ìbílẹ̀ dárà lati gbé àṣà lárugẹ

Ọjọ́ kọkànlélógun, oṣù karùn ún ní ọdọọdún ni àyájọ́ ọjọ́ àṣà ní àgbáyé, bí àwọn olùgbé Ipinlẹ̀ náà ṣe rántí ọjọ́ náà rèé.

Ayajọ ọjọ Àṣa ní Ipinlẹ Oyo
Àkọlé àwòrán, Iṣẹ́ yá, aṣọ ilẹ̀ Yoruba kò ní ká ma ṣiṣẹ́
Ayajọ ọjọ Àṣa ní Ipinlẹ Oyo
Àkọlé àwòrán, Ọkan lara àwọn oṣiṣẹ Ipinlẹ Oyo yii ni aṣọ wiwọ ati aṣa bii iya ati ọmọ ni.
Ayajọ ọjọ Àṣa ní Ipinlẹ Oyo
Àkọlé àwòrán, Arabinrin yii ni oun na ko gbẹyin
Ayajọ ọjọ Àṣa ní Ipinlẹ Oyo
Àkọlé àwòrán, Ẹrin muṣẹ!
Ayajọ ọjọ Àṣa ní Ipinlẹ Oyo
Àkọlé àwòrán, Ojulowo ọmọ Yoruba naa ni awa
Ayajọ ọjọ Àṣa ní Ipinlẹ Oyo
Àkọlé àwòrán, Aṣa Yoruba rẹwa
Ayajọ ọjọ Àṣa ní Ipinlẹ Oyo
Àkọlé àwòrán, 'ÀbÍ a ò rẹwà báyìí?'
Ayajọ ọjọ Àṣa ní Ipinlẹ Oyo
Àkọlé àwòrán, Pẹlu ilu ati ijo ni wọn fi gbe aṣa laruge
Ayajọ ọjọ Àṣa ní Ipinlẹ Oyo
Àkọlé àwòrán, Orukọ mi ni ẹlẹrin ẹyẹ.