You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
9ice: Ǹjẹ́ olórin tàkasúfèé yìí ń mu igbó bí àwọn òṣèré mìíràn?
Abolore Adegbola Akande ti awọn ololufẹẹ rẹ mọ si 9ice sọrọ nipa igbesi aye rẹ àti ero rẹ nipa bí àwọn oṣere kan ṣe maa n mu igbo ati ọtin ki wọn to ṣere.
Ọpọ gbagbọ wipe, ko ṣeeṣe ki olorin dárà lai mu igbo tabi ọtin. 9ice fi èro rẹ han lori ọrọ yii.