You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Falz tó jẹ́ olórin tàka-súfèé ti kéde pé òun ń wá obìnrin rere lọ́ọ̀dẹ̀ òun
Falz sọ orisirisi nkan nipa ara rẹ, ati wipe oun n wa iyawo. O tun salaye iru obinrin ti oun n wa.
Iru awọn iroyinti ẹ le nifẹ si:
Omọ Falana yii ti kopa ninu ere fiimu agbelewo ati ere oniṣe loriṣiirisi bii ti Jẹnifa.
Ọpọ orin to n fọ awujọ mọ loriṣiiriṣii ni Falz ti gbe sita ṣaaju asiko yii.
Obinrin to ba ni awọn amuyẹ ti Fọlarin Falana (Falz) ka silẹ lasiko to n ṣabẹwo sile iṣẹ BBC nilu Eko yii le jade sita nitori a ko kuku mọ ori ọlọla ni ọrọ ile aye.