House on water: Ǹjẹ́ ìwọ lè gbé ilé tó wà lórí omi?
Ajọ iṣọkan agbaye ni eeyan bi ẹgbẹrun mẹwaa ni yoo maa gbe ile to wa lori omi laipẹ laijina.
Ilu ti yoo wa lori omi yii ni yoo maa ṣe ipese ounjẹ ati ina ati omi pẹlu dida idọti rẹ nu lọna igbalode fun ara rẹ.
Ajọ iṣọkan agbaye ni ilu yii le jẹ ọna abayọ si ẹkun omi to n de ba okun.
Awọn eeyan to n gbe lagbegbe omi ni yoo kọkọ jẹ anfani yii.
- Ààrẹ Buhari kẹ́dùn pẹ̀lú ẹbí àwọn èèyàn 207 tí wọ́n pa lọ́jọ́ Àjíǹde
- Àkójọpọ̀ àwòrán ọdún ọdún Àjínde l'Afrika
- Ẹlẹ́wọ̀n bí ìbejì làǹtì lànti!
- Omotola Jalade ní Nàìjíríà dàbí ọ̀run àpáàdì lábẹ́ ìjọba Buhari
- Ibrahim Chatta fesi sí ẹ̀sùn pé òun na iyawo rẹ̀!
- Helen Paul: Ọmọ atàpáta dìde ni mí, ẹ má fójú ajẹbọ́ wò mí