Building Collapse: Àlàyé rèé lórí bí ilé kẹ̀ta ti wó l'Eko
Ile yii ti wá ní abé àwọn ile ti wọn ti pinu láti wo teletele kò tó di pé ó dawo ni ìrólé yii. Kò sí ẹ̀mí tó sínú níbi ilé náà. Àwọn tí oro naa soju wọn sọ pé àwon mẹ́rin ni ile naa wolu lásìkò tí wọn ń gbìyànjú láti ṣe àwo pale rẹ.
Wọn ní ní kété tí ẹni tó ní ilé náà ṣe gbó pé ìjọba tí yaa soto láti wòó ni ó fi kú àwọn tí yóò bá ṣe iṣẹ́ ilé Wiwo náà.