You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Issa Aremu ṣàlàyé kíkún nípa èròńgbà ẹgbẹ́ Labour to bá jáde
O ṣakawe nipa àwọn agba oloṣelu ati iṣẹ wọn fun BBC Yoruba lasiko ifọrọwanilẹnuwo naa.
Issa Arẹmu ti figba kan jẹ igbakeji aarẹ ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ ti a mọ si Nigeria Labour Congress.
O n dije dupo gomin alabẹ ẹgbẹ oṣelu Labour Party ni Kwara.
- Ẹgbẹ́ APC dá ọmọ Alao Akala padà sípò alága Ogbomọṣọ North
- Ọjọ́ Àbámẹ́ta la ó mọ ẹni tí yóò lékè láàrín bàbá ìsàlẹ̀ àti àwọn mẹ̀kúnnù nipinlẹ̀ Ọyọ. – Seyi Makinde
- Ètò tí mo ní fún Kwara yàtọ̀ sí ti ANRP ni mo ṣe fẹgbẹ́ wọ́n sílẹ̀ - Yinka Ajia
- 2019 Elections: NBC na Channels TV àti ilé iṣẹ́ ìròyìn 44 ní pàsán
Bi ọmọ kò bá ba itan, o di dandan kó ba àrọ́bá to jẹ́ baba ìtàn, Issa Arẹmu ṣalaye fun BBC pe oloṣelu to fẹ ṣaṣeyọri gbọdọ ṣetan lati sin awọn eniyan rẹ ni.
O fi Oloye Ọbafẹmi Awolowọ ati Saudana Sokoto ṣe akawe awọn oloṣelu ti ipa wọn ko le parẹ lai.
Issa Arẹmu ni ẹni to ba laya lo n dije dupo.
O mẹnuba gbogbo nkan ti oun ati ẹgbẹ rẹ ni lọkan lati ṣe fun awọn eniyan ipinlẹ Kwara ti oun ba wọle.
- Ohun márùn-ún tí Atiku ń bèrè lọ́wọ́ Buhari níbi ìpàdé rẹ̀ pẹlú Abdulsalam, Kukah
- APC pàṣẹ lọ rọ́ọ́kún nílé fún Amosun, Okorocha
- Ǹjẹ́ o mọ̀ pé ọdọ 43m ló wà lára olùdìbò?#BBCNigeria2019
- #BBC Nigeria Decides: Akala darapọ̀ mọ́ APC fún ìbò gómìnà
- #BBCNigeria2019: BBC ṣetán láti mu gbogbo ètò ìdìbò bó ṣe n lọ wa!