NigeriaDecides2019: Kátàkátà ti bẹ̀rẹ̀ láwọ̀n agbègbè míì, tí ìlú míì sì dá
Published
Aarọ ọjọ idibo aarẹ gan ni ajọ eleto idibo Naijiria kede pe eto idibo naa ko ni lee waye mọ.
Àkọlé àwòrán, Àwọn agbófinró rèé nó Ondo, tí wọn dí ojú ọ̀nà áíbaàmọ̀....Àkọlé àwòrán, Awọn agbofinro ree, ti wọn duro gbagba gbaa sile iṣẹ ajọ eleto idiboÀkọlé àwòrán, Awọn ọlọpa tun ree ti wọn di oju ọna ladugbo miran, laimọ pe......Àkọlé àwòrán, Abẹ atibaba yii ni awọn oludibo n gbero lati fori pamọ si lasiko idibo nitori oorun, amọ riro ni ti eniyan, ṣiṣe ni ti ỌlọrunÀkọlé àwòrán, Inu gbọngan yii ni ajọ eleto idibo ti seto rẹ silẹ pe wọn yoo ti kede apapọ esi ibo nipinlẹ Ondo, amọ bi wọn ti n fẹ, kọ lo riÀkọlé àwòrán, Idaji kutukutu lawọn eeyan ipinlẹ Ondo ti bọ sita lati wa se ojuse wọn, amọ o seni laaanu pe ajọ Inec ja wọn ni tanmọÀkọlé àwòrán, Ajimuna lawọn eeyan fi eto idibo aarẹ se ni Ondo, sugbọn o ye ỌlọrunÀkọlé àwòrán, Ero ree nita, ti wọn fẹ dibo. O ma se o.Àkọlé àwòrán, Paroparo ni ileepo da ni OndoÀkọlé àwòrán, Araalu ati Sọja n wo ara wọn. Ki lo de o?Àkọlé àwòrán, Awọn eeyan ilu Ibadan ko tilẹ fi akoko sofo, kia ni awọn kẹkẹ Maruwa ti jade lati sisẹ nigba ti ibo ko waye mọMóríwú