You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ìfipálówó: Bàbá ọmọ tí wọn gé lórí ní òun rán an láti gbowó lẹ́nu ATM ni
Ọjọ buruku, esu gbomi mu ni ọjọ kẹtadinlọgbọn osu Kọkanla ọdun 2018, ladugbo Ọbakunle Drive, Sapati, Ibẹju-Lekki nilu Eko, nigba tọwọ ọlọpaa tẹ ọmọ iya meji ti wọn bẹ ori ọmọ aladugbo wọn.
Kayọde Makinde, tii se baba ọmọ ti wọn bẹ lori naa, lasiko to n ba BBC Yoruba sọrọ pẹlu omije loju ni, oun ran ọmọ oun lati lọ gba owo wa lẹnu ẹrọ ATM, lo ba di awati.
Aago mọkanla alẹ tawọn ọlọpaa safihan ori ọmọ naa, ti wọn ti ge, lo to mọ pe ina jo oun, to si mu wa de ile akọpati ti wọn ti ge ori ọmọ rẹ.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ìbejì Oníbẹ̀mbẹ́ Òru tí kò yara wọn lẹ́yìn ọgọ́ta ọdún
- Ohùn ìjálá lásán ni mo fi ń pa ẹran nínú igbó - Ọdẹ Oníjàálá
- Mo fẹ́ ọkọ mi torí bó se ń kọrin, kìí se torí owó - Ìyàwó Aràrá
- Mo fẹ́ kí àyẹyẹ ìgbeyàwó mi dùn ni mo se bú sẹ́kún - Ọkọ ìyàwó ẹlẹ́kún
- Samuel Ladoke Akintọla jẹ́ Agbẹjọ́rò àti Akọ̀ròyìn tí ọ̀rọ̀ dá lẹ́nu rẹ̀
- Hubert Ogunde rèé, baba àwọn òsèré tíátà
- Ìyàtọ̀ wà nínú ìlépa àwọn òṣèré tíátà ayé àtijọ́ àti ìsisìnyí-Papalolo
O fi kun pe ọkan ninu awọn ọmọ iya meji naa bimọ, to si n wa owo ikomọ tii se ẹgbẹrun lọna igba naira, ni eeyan kan to n wa ori eeyan ba bẹẹ nis pe to ba lee gbe ori wa, yoo gba owo naa.
Iya Joseph, naa salaye pe, gbogbo igba ni oun maa n la ala ri ọmọ to ti ku naa, to n rin kiri plu ẹkun kikoro