BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ọṣun State: Gboyega Oyetọla di Gómìnà Ọṣun
27 Bélú 2018
Ìgbà tí a ṣe àfíkun gbẹ̀yìn 28 Bélú 2018
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀lúmọ̀ọ́ka ló péjú pésẹ̀ síbi ètò ìbúra wọlé fún Gómìnà Gboyega Oyetọla.
Àkọlé àwòrán,
Alhaji Gboyega Oyetọla n lọ bura gẹgẹ bii gomina tuntun ipinlẹ Ọsun.
Àkọlé àwòrán,
Lara awọn eeyan pataki ti o tun darapọ mọ ipejọpọ naa ni Ọọni Ile Ifẹ, Ọba Enitan Ogunwusi.
Àkọlé àwòrán,
Adari ẹgbẹ oṣelu APC, Bọla Tinubu
Àkọlé àwòrán,
Gomina Ganduje ti ipinlẹ Kano nibi ibura wọle Gomina Gboyega Oyetọla
Àkọlé àwòrán,
Gomina Gboyega Oyetọla n tọwọ bọwe
Àkọlé àwòrán,
Gomina Rotimi Akeredolu ti ipinlẹ Ondo náà kò gbẹ́yìn
Àkọlé àwòrán,
Gomina ipinlẹ Eko, Akinwumi Ambode
Àkọlé àwòrán,
Gomina ipinlẹ Ọyọ lewaju, ti Ekiti tẹle e, Gomina Eko si n wo wọn lọọkan
Àkọlé àwòrán,
Gbajugbaja osere Yoruba Fadeyi Oloro niyii lẹgbẹ Ataoja ti Osogbo, Oba Jimoh Olanipekun pẹlu iyawo rẹ
Àkọlé àwòrán,
Gboyega Oyetọla bura wọle gẹgẹ bii gomina tuntun ipinlẹ Ọsun.
Àkọlé àwòrán,
Gbajugbaja osere Yoruba Fadeyi Oloro
Àkọlé àwòrán,
Awọn eniyan ipinlẹ Ọṣun sọ ohun ti wọn n reti lọwọ gomina tuntun
Àkọlé àwòrán,
Ara ipinlẹ̀ Ọṣun
You might also like:
news
|
sport
|
weather
|
worklife
|
travel
|
future
|
culture
|
world
|
business
|
technology