Ọ́lọ́jọ́2018: Aṣọ ń pe aṣọ ránṣẹ́ nílé Ifẹ̀

Ìlú Ilé Ifẹ̀ sọkutu wọ̀wọ̀, tí ẹsẹ̀ kò sò gbèrò lásìkò ọdun Ọlọ́jọ́.

Awọn Obirin ninu ànkòó
Àkọlé àwòrán, Ẹni to ba kan ẹgbẹ awọn obinrin nibi ijoko wọn, yoo ki aje ku ikalẹ pẹlu asọ olowo iyebiye ti wọn ko si
Awọn obinrin ninu aṣọ ẹgbkjọda
Àkọlé àwòrán, Onírúuru ẹgbẹ́jọda àṣọ làwọn ènìyàn wọ fún ayẹyẹ tó wọlé dé
Ere oodua
Àkọlé àwòrán, Ere òòdua rèé o tí tọka si ibi ti ọmọ Yorùba ti ṣẹ̀ wá
Awọn ẹgbẹ́ awo ninu aṣọ funfun
Àkọlé àwòrán, Àwọn Isòrò ń dúró de Oònirìsà lati kìí fún ayẹyẹ ọdun Ọlọ́jọ
Awọn obninrin ninu asọ funfun àti Ankara
Àkọlé àwòrán, Awọn awo lóbìnrin náà rèé láàyè wọn lati júba Ọ̀òni
Gbagede eto fun ayẹyẹ Ọlọ́jọ́
Àkọlé àwòrán, Gbàgede àyẹyẹ náà rèé oo, gbogbo ènìyàn ló ti wà ní ṣẹpẹ́
Awọn eeyan duro siwaju aafin Ọọni
Àkọlé àwòrán, Aafin Ọọni naa n sọkutu wọwọ fun ọdun Ọlọjọ
Awọn eeyan to joko nibi ọdun Ọlọjọ
Àkọlé àwòrán, Awọn ẹni bi ẹni, eeyan bii eeyan ko gbẹyin nibi ayẹyẹ ọdun Ọlọjọ
Awọn ẹgbẹ awo miran
Àkọlé àwòrán, Awọn Oloye naa joko sẹpẹ
Awọn eeyan to joko nibi ọdun Ọlọjọ
Àkọlé àwòrán, Asọ funfun ree to duro wawa lara awọn oloye
Awon obinrin nin u asọ funfun
Àkọlé àwòrán, Ẹ kore Yeye o
Awon obinrin ninu asọ funfun
Àkọlé àwòrán, Oju pe, ẹsẹ pele ni ọdun Ọlọjọ
Awon obinrin ninu asọ funfun
Àkọlé àwòrán, Awọn irun ibilẹ yii rẹwa, wọn jẹ oju ni gbese.
Oyinbo ni ọdun Ọlọjọ
Àkọlé àwòrán, Awọn ọmọ ilẹ okeere ko gbẹyin ni ọdun Ọlọjọ
Oyinbo ni ọdun Ọlọjọ
Àkọlé àwòrán, Oyinbp ree, to wọ asọ ibilẹ wa
Oyinbo ni ọdun Ọlọjọ
Àkọlé àwòrán, Ẹrin oyinbo yii nibi ọdun Ọlọjọ fa ni mọra
Oyinbo ni ọdun Ọlọjọ
Àkọlé àwòrán, Awọn Ajeji to wa sibi ọdun ọlọjọ kii se keremi
Ọba Adeyẹye Ogunwusi
Àkọlé àwòrán, Kabiyesi, Alayeluwa, Ọọni tilu Ifẹ ń ki àwọn araalu ku ọdun
Ọba Adeyẹye Ogunwusi
Àkọlé àwòrán, Awọn araalu n se Kabiesi si Ọọni