Ikú Fẹlẹ́: Awọn èèkàn ìlú ṣelédè lẹ́yìn Taofeek Oyerinde Fẹlẹ

Awọn ọmọ ẹgbẹ́ àwakọ̀ jákèjádò Nàìjíríà atawọn eekan ilu ni wọn peju pesẹ sibi isnku alaga ẹgbẹ ọlọkọ ero lẹkun iwọ oorun Guusu Naijiria.

Awọn èrò níbi òkú
Àkọlé àwòrán, Àwọn ènìyàn ìlú Ibadan bárajẹ́ níbi òkú Fẹ́lẹ́. Báwọn míràn ṣe ń sunkun làwọn míràn gbára dalẹ̀
Awon èrò tó wá kẹ́dùn
Àkọlé àwòrán, Ìmúra sílẹ̀ láti gbé òkú wọlẹ̀ nínú ilé Taofeek Ayorinde
Fọto Fẹ́lẹ́
Àkọlé àwòrán, Fẹ́lẹ́ kú ní àná lẹ́yìn àìsan kíndìnrín nílùú Abuja
Ero rèé nílé Fẹ́lẹ́
Àkọlé àwòrán, Háà, báa kú làá dère, àwọn olólufẹ Fẹ́lẹ́ rèé ooo
Eniyan nilé tó wá si bi oku
Àkọlé àwòrán, Ọ̀pọ̀ ènìyàn ló jẹ́ri si gbogbo iṣẹ́ ríbiribi tí alága àwọn awakọ̀ Ipínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti ṣe
gbogbo àwọn ero pe bìbà sílẹ́ rẹ̀
Àkọlé àwòrán, Ọmọ ẹgbẹ́ awakọ̀ jákèjádò Nàìjíríà péjú níbi ìsìnkú Taofeek Oyerinde