BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ọ̀ṣun-Òsọgbo: Àwọn àwòrán tó gbayì níbi ọdún Ọ̀ṣun-Òṣogbo
17 Ògún 2018
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ló n kópa níbi ọdún Ọ̀ṣun-Òṣogbo fún ọdún 2018
Àkọlé àwòrán,
Èyí ni ibùdó tí àwọn tó n kópa níbi ọdún Ọ̀ṣun-Òṣogbo 2018 tí n gba àdúrà sí Ọ̀ṣun
Àkọlé àwòrán,
Àwọn ènìyàn n gba àdúrà sí òrìṣà Ọ̀ṣun
Àkọlé àwòrán,
Àwọn irun alárànbarà ló péjú síbi ọdún nàá
Àkọlé àwòrán,
Òrékelẹ́wà
Àkọlé àwòrán,
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ló n kópa níbi ọdún Ọ̀ṣun Òṣogbo
Àkọlé àwòrán,
Àwọn àwòrán tó gbayì níbi ọdún Ọ̀ṣun-Òṣogbo
You might also like:
news
|
sport
|
weather
|
worklife
|
travel
|
future
|
culture
|
world
|
business
|
technology