Lẹnu ọjọ mẹta yí, ipaniyan láwọn agbègbè kàn lorílè-èdè Nàìjíríà jẹ òun tó kàn òpó èèyàn lominu
Àkọlé àwòrán, Awọn ara ilu ati ajọ ajafeto ọmoniyan orisirisi kopa ninu iwọde naa
Àkọlé àwòrán, Gulegule awọn darandaran ti da oniruuru ipaya silẹ kaakiri orilẹede Naijiria
Àkọlé àwòrán, Lẹnu ọjọ mẹta yí, ipaniyan láwọn agbègbè kàn lorílè-èdè Nàìjíríà jẹ òun tó kàn òpó èèyàn lominu
Àkọlé àwòrán, Ẹgbẹ awọn ọmọlẹyin Kristi ni orilẹede Naijiria, CAN so laipe yi pe asiko to fun gbogbo igun ati ijọ lati pa ohun pọ sọrọ lori awọn ipaniyan yii.
Àkọlé àwòrán, Ati musulumi ati Kristeni lo wa ninu awọn to kọwọrin nibi iwọde Abuja yi