Àbẹwo Macron Awọn àwòrán tó jẹ ojú ní gbèsè ní Kalakuta

Ààrẹ Faransé se abewo si Naijiria nibi to ti sepade pelu aare Muhammadu Buhari ni ilu Abuja.

Àwọn oníjó ìbílẹ̀
Àkọlé àwòrán, Àwọn oníjó ìbílẹ̀ kí àwọn àlejò kúàbọ̀ si ile igbafẹ Afrika Shrine
Ndị egwu
Àkọlé àwòrán, Ndị egwu nabatara onyeisiala mba Frans bụ Emmanuel macron
Emmanuel Macron

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Onyeisiala mba Frans gara Afrika Shrine ụlọ onye otiegwu a ma ama na Naịjirịa lara mmụọ bụ Fela Anikulapo Kuti
Àwọn oníjó ìbílẹ̀
Àkọlé àwòrán, Ijo ibilẹ Yoruba ni wọn fi ki Aarẹ ilẹ Faranse, Emmanuel Macron ku abọ
Emmanuel Macron

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Gomina ipinlẹ Eko, Akinwunmi Ambode ati awọn eniyan jankanjankan lo ki Macron ku abọ.
Macron na Angelique Kidjo

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Macron pelu Gomina Ambode ati gbajugbaja olosere Angelique Kidjo ni Afrika Shrine
Emmanuel Macron n'arụsị Fela

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Emmanuel Macron ko gbeyin lati kọ ijo igbalode ti wọn pe ni ‘Shakushaku’
Emmanuel macron

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ọmọdékùnrin tó ń fi àwòrán dárà,Waris Kareem náà bá àwọn ọlọ́lá péjọ pọ̀ ní Africa Shrine
Emmanuel Macron ati Kareen

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Emmanuel Macron kan sáárá lórí àwòrán ti ọdọmọde naa yà
Femi Kuti

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Seun Kuti ni kii ṣe Macron ni aarẹ France akọkọ ti yoo bẹ Fela wo
Femi Anikulapo Kuti

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ọmọ Fela Anikulapo to jẹ olorin igbalọde lo tun ibudo igbafẹ se, to si pe e ni ‘New Afrika Shrine’
Emmanuel macron na arụsị Fela na Legos

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ibaṣepọ to gbooro wa laarin idile Fela Kuti ati awọn aarẹ orilẹede France
Femi Kuti

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Gbogbo àwọn tó wà níbí ètò fún àjọsepọ̀ àgbéga àṣà láàrin orilẹ̀èdè Nàìjíríà àti ilẹ̀ Faranse dára yá pẹ̀lú ijó ìbílẹ̀ Yorùbá.
Emmanuel macron

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Àsà Yorùbà gbayì lójú Ààrẹ ilẹ̀ Faranse
Emmanuel Macron, Femi Kuti ati Youssou N'dour

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Emmanuel Macron ya aworan pẹlu Femi Kuti ati gbajugbaja olorin lati orilẹede Senegal, Youssou N'dour
Emmanuel macron

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Orisirisi aworan ni pẹrẹwu pẹlu awọn ilumọọka olorin takasufe ni ilẹ Afirika
Emmanuel macron

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Femi Kuti ati Emmanuel macron ya 'selfie'