BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Iná Èkó: Rẹ́rẹ́ rún níbi ìjàmbá iná l‘Ékó
28 Òkùdu 2018
Agbègbè Ìkóríta Ọ̀tẹ́dọla, Berger, ní opópónà márosẹ̀ Ìbàdàn sí ìlú Èkó ni ìsẹ̀lẹ̀ náà ti wáyé.
Àkọlé àwòrán,
Rẹrẹ run, ẹ ni kan lo mọ, ọ̀pọ̀ ọkọ̀ lo jona
Àkọlé àwòrán,
Awọn osisẹ adoola ẹm iati panapana ri isẹ se nibi isẹlẹ ina ọhun
Àkọlé àwòrán,
Dukia run, ẹmi bọ́ ninu isẹlẹ naa
Àkọlé àwòrán,
Oju ọrun gan mọ pe isẹlẹ abami gan n sẹlẹ
Àkọlé àwòrán,
Haa, afi ki Ọlọrun fi ofo rẹmi
Àkọlé àwòrán,
Bi eeyan ba j ori ahun, yoo sunkun nibi isẹlẹ naa
Àkọlé àwòrán,
Ki Ọlọrun dẹ ilẹ fawọn eeyan to se agbako isẹlẹ naa
Àkọlé àwòrán,
Nkan nla
Àkọlé àwòrán,
Ko sẹni to le gba oju ọna ti isẹlẹ́ naa ti waye kọja
Àkọlé àwòrán,
O le ni ogun ọkọ to jona nibi isẹlẹ ina Eko
You might also like:
news
|
sport
|
weather
|
worklife
|
travel
|
future
|
culture
|
world
|
business
|
technology