You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Olumide Ọrẹsẹgun: Ẹni mọ iyì wúrà ni mo ń ta awòrán fún
Olumide Orẹṣẹgun, gbajúgbajà ayàwòrán sọ̀rọ̀ lórí oríṣii àwòrán tó wa àti ìmísí lórí àwòrán yíyà.
Ọrẹsẹgun ni ni ọpọlọ, suuru àti agbára ni oun ń lò lati fi de ipo ti oun ti de bayii.